Igbó Ojúbọ Òrìṣà Osun Osogbo ní Nàìjíríà
Igbó Ojúbọ Òrìṣà Osun Osogbo jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn igbó ojúbọ òrìṣà tó kù ní Nàìjíríà. Igbó Ojúbọ náà jẹ́ ilé fún ọ̀pọ̀ ojúbọ̀ ère ńlá tí a kọ́ fún ọlá àwọn irúnmọlẹ̀ láti orísun Yoruba. Àwọn ojúbọ náà ṣàfihàn àwọn ọ̀nà ìṣẹ̀nbáyé, wọ́n sì kún fún àwọn ààmì àti ìtumọ̀.
3D model of the shrine to Iya Moopo, godess of women's occupations (2019-12) by CyArkCyArk
Ìṣàwárí Iya Moopo
Ère Iya Moopo ní Osogbo jẹyọ nínú igbó. Iya Moopo jẹ́ “Ìyá Ńlá” nínú ìtàn Yoruba, ó sì ń dáabòbo àwọn obìnrin nínú ohun gbogbo tí wọ́n gbọ́dọ̀ ṣe, láti ọmọ-bíbí títí lọ bá iṣẹ́ tàbi òwò wọn.
Oríṣi ọwọ́ mẹ́ta
Ojúbọ náà ní Osogbo ni a ṣàfihàn pẹ̀lú ọwọ́ mẹ́ta láti ṣàpẹrẹ fífúnni ní ìmọ̀ràn, ìbùnkún àti ọ̀rọ̀ ìyànjú.
Àwọn Ère ẹlẹ́yẹ
Ère náà tún ṣàfihàn àwọn aṣojú Atiala àti Atioro, àwọn ère tó dàbí ẹyẹ tí a fihàn bí èyí tó bà sára ojúbọ náà.
Àwọn Ère ẹlẹ́yẹ
Gẹ́gẹ́ bí àṣà Yoruba, Atiala àti Atioro jẹ́ àwọn olùrànlọ́wọ́ ẹyẹ, a sì tún rí wọn bíi ohun mímọ́.
Kọ́ ẹ̀kọ́ Síi pẹ̀lú Ayàworán àti Ajìjàgbara Molara Wood
Open Heritage 3D Graphic by CyArkCyArk
Ṣe àkópọ̀ Détà 3D fún Araàrẹ
You are all set!
Your first Culture Weekly will arrive this week.